Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 4:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Debora wí fún Baraki pé, “Dìde nítorí pé òní ni ọjọ́ tí OLUWA yóo fi Sisera lé ọ lọ́wọ́. Ṣebí OLUWA ni ó ń ṣáájú ogun rẹ lọ?” Baraki bá sọ̀kalẹ̀ láti orí òkè Tabori pẹlu ẹgbaarun (10,000) ọmọ ogun lẹ́yìn rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 4

Wo Àwọn Adájọ́ 4:14 ni o tọ