Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 3:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ehudu bá tọ̀ ọ́ lọ, níbi tí òun nìkan jókòó sí ninu yàrá tútù kan, lórí òrùlé ilé rẹ̀, ó wí fún un pé, “Ọlọ́run rán mi ní iṣẹ́ kan sí ọ,” ọba bá dìde níbi tí ó jókòó sí.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:20 ni o tọ