Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 3:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun nìkan bá pada ní ibi òkúta tí wọ́n gbẹ́, tí ó wà lẹ́bàá Giligali, ó tọ ọba lọ, ó ní, “Kabiyesi, mo ní iṣẹ́ àṣírí kan tí mo fẹ́ jẹ́ fún ọ.”Ọba bá sọ fún gbogbo àwọn iranṣẹ rẹ̀ tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ pé kí wọ́n jáde, gbogbo wọn sì jáde.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 3

Wo Àwọn Adájọ́ 3:19 ni o tọ