Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn olórí láàrin àwọn eniyan náà jákèjádò ilẹ̀ Israẹli kó ara wọn jọ pẹlu ìjọ eniyan Ọlọ́run. Àwọn ọmọ ogun tí wọn ń fi ẹsẹ̀ rìn, tí wọ́n sì ń lo idà, tí wọ́n kó ara wọn jọ níbẹ̀ tàwọn ti idà lọ́wọ́ wọn jẹ́ ogún ọ̀kẹ́ (400,000).

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:2 ni o tọ