Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 20:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jáde wá, bẹ̀rẹ̀ láti Dani ní apá ìhà àríwá títí dé Beeriṣeba ní apá ìhà gúsù ilẹ̀ Israẹli ati àwọn tí wọ́n wà ní ilẹ̀ Gileadi, ní apá ìwọ̀ oòrùn. Wọ́n kó ara wọn jọ sójú kan ṣoṣo níwájú OLUWA ní Misipa.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 20

Wo Àwọn Adájọ́ 20:1 ni o tọ