Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

ati pé, ẹ kò gbọdọ̀ bá èyíkéyìí ninu àwọn tí wọn ń gbé ilẹ̀ yìí dá majẹmu kankan, ẹ sì gbọdọ̀ wó gbogbo pẹpẹ wọn lulẹ̀.’ Ṣugbọn ẹ kò mú àṣẹ tí mo pa fun yín ṣẹ. Irú kí ni ẹ dánwò yìí?

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 2

Wo Àwọn Adájọ́ 2:2 ni o tọ