Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 2:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Angẹli OLUWA gbéra láti Giligali, ó lọ sí ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Israẹli ní Bokimu, ó sọ fún wọn pé, “Mo ko yín jáde láti ilẹ̀ Ijipti, wá sí ilẹ̀ tí mo ti búra fún àwọn baba ńlá yín pé n óo fún wọn. Mo ní, ‘N kò ní yẹ majẹmu tí mo bá yín dá,

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 2

Wo Àwọn Adájọ́ 2:1 ni o tọ