Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 18:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá wọn lóhùn pé, “Ẹ dìde, ẹ jẹ́ kí á lọ gbógun tì wọ́n nítorí pé a ti rí ilẹ̀ náà, ilẹ̀ tí ó lọ́ràá ni. Ẹ má jẹ́ kí á fi ọ̀rọ̀ náà falẹ̀. Ẹ má jáfara, ẹ wọ ilẹ̀ náà, kí ẹ sì gbà á.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 18

Wo Àwọn Adájọ́ 18:9 ni o tọ