Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 18:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn ọkunrin marun-un náà pada dé ọ̀dọ̀ àwọn eniyan wọn ní Sora ati Eṣitaolu, àwọn eniyan wọn bi wọ́n léèrè pé, “Báwo ni ọ̀hún ti rí?”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 18

Wo Àwọn Adájọ́ 18:8 ni o tọ