Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 18:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n lọ pàgọ́ sí Kiriati Jearimu ní Juda. Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń pe ibẹ̀ ní Mahanedani títí di òní olónìí; ó wà ní apá ìwọ̀ oòrùn Kiriati Jearimu.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 18

Wo Àwọn Adájọ́ 18:12 ni o tọ