Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 17:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mika bá bi í pé, “Níbo ni o ti ń bọ̀?”Ó dá a lóhùn pé, “Ọmọ Lefi, láti Bẹtilẹhẹmu ní ilẹ̀ Juda ni mí, ibi tí n óo máa gbé ni mò ń wá kiri.”

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 17

Wo Àwọn Adájọ́ 17:9 ni o tọ