Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 17:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọdọmọkunrin náà kó kúrò ní Bẹtilẹhẹmu ní ilẹ̀ Juda, láti lọ máa gbé ibikíbi tí ó bá ti rí ààyè. Bí ó ti ń lọ, ó dé ilé Mika ní agbègbè olókè ti Efuraimu.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 17

Wo Àwọn Adájọ́ 17:8 ni o tọ