Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 15:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n dá a lóhùn pé, “Rárá, àwa óo dì ọ́, a óo sì gbé ọ lé wọn lọ́wọ́ ni, a kò ní pa ọ́ rárá.” Wọ́n bá mú okùn titun meji, wọ́n fi dì í, wọ́n sì gbé e jáde láti inú ihò àpáta náà.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 15

Wo Àwọn Adájọ́ 15:13 ni o tọ