Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 14:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá yọ́ ninu afárá oyin náà sí ọwọ́, ó bẹ̀rẹ̀ sí lá a bí ó ti ń lọ. Nígbà tí ó bá baba ati ìyá rẹ̀, ó fún wọn lá ninu rẹ̀; ṣugbọn kò sọ fún wọn pé ara òkú kinniun ni òun ti rẹ́ afárá oyin náà.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 14

Wo Àwọn Adájọ́ 14:9 ni o tọ