Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 14:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Baba rẹ̀ bá lọ sí ọ̀dọ̀ obinrin náà. Samsoni se àsè ńlá kan níbẹ̀, nítorí pé bẹ́ẹ̀ ni àwọn ọdọmọkunrin máa ń ṣe nígbà náà.

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 14

Wo Àwọn Adájọ́ 14:10 ni o tọ