Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Adájọ́ 11:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Fún nǹkan bí ọọdunrun (300) ọdún tí Israẹli fi ń gbé Heṣiboni ati Aroeri, ati àwọn ìletò tí ó wà ní agbègbè wọn, ati àwọn ìlú ńláńlá tí ó wà ní etí odò Anoni, kí ló dé tí o kò fi gba ilẹ̀ rẹ láàrin àkókò náà?

Ka pipe ipin Àwọn Adájọ́ 11

Wo Àwọn Adájọ́ 11:26 ni o tọ