Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 5:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ìwà àìdára yín ni mo mọ̀, mo sì mọ̀ bí ẹ̀ṣẹ̀ yín ti tóbi tó, ẹ̀yin tí ẹ̀ ń fìyà jẹ olódodo, tí ẹ̀ ń gba owó àbẹ̀tẹ́lẹ̀, tí ẹ sì ń du àwọn aláìní ní ẹ̀tọ́ wọn lẹ́nu ibodè.

Ka pipe ipin Amosi 5

Wo Amosi 5:12 ni o tọ