Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 5:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ̀ ń rẹ́ talaka jẹ, ẹ sì ń fi ipá gba ọkà wọn. Nítòótọ́, ẹ ti fi òkúta tí wọ́n dárà sí kọ́ ilé, ṣugbọn ẹ kò ní gbé inú wọn; ẹ ti ṣe ọgbà àjàrà dáradára, ṣugbọn ẹ kò ní mu ninu ọtí waini ibẹ̀.

Ka pipe ipin Amosi 5

Wo Amosi 5:11 ni o tọ