Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 4:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, n óo jẹ yín níyà, ẹ̀yin ọmọ Israẹli; nítorí irú ìyà tí n óo fi jẹ yín, ẹ múra sílẹ̀ de ìdájọ́ Ọlọrun yín, ẹ̀yin ọmọ Israẹli!”

Ka pipe ipin Amosi 4

Wo Amosi 4:12 ni o tọ