Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n rẹ́ àwọn talaka jẹ, wọ́n sì yí ẹjọ́ àwọn tí ìyà ń jẹ po. Baba ati ọmọ ń bá ẹrubinrin kanṣoṣo lòpọ̀, wọ́n sì ba orúkọ mímọ́ mi jẹ́.

Ka pipe ipin Amosi 2

Wo Amosi 2:7 ni o tọ