Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Amosi 2:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní: “Àwọn ará Israẹli ń dẹ́ṣẹ̀ kún ẹ̀ṣẹ̀, dájúdájú, n óo jẹ wọ́n níyà; nítorí pé wọ́n ta olódodo nítorí fadaka, wọ́n sì ta aláìní nítorí bàtà ẹsẹ̀ meji.

Ka pipe ipin Amosi 2

Wo Amosi 2:6 ni o tọ