Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 65:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó, àwọn iranṣẹ mi yóo máa rí oúnjẹ jẹ,ṣugbọn ebi yóo máa pa yín;àwọn iranṣẹ mi yóo mu waini,ṣugbọn òùngbẹ yóo máa gbẹ yín.Àwọn iranṣẹ mi yóo máa yọ̀,ṣugbọn ìtìjú yóo máa ba yín.

Ka pipe ipin Aisaya 65

Wo Aisaya 65:13 ni o tọ