Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 65:12 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fi yín fún ogun pa,gbogbo yín ni ẹ óo sì bọ́ sọ́wọ́ àwọn apànìyàn;nítorí pé nígbà tí mo pè yín, ẹ kò dáhùn,nígbà tí mo sọ̀rọ̀, ẹ kò gbọ́,ẹ ṣe nǹkan tí ó burú lójú mi;ẹ yan ohun tí inú mi kò dùn sí.

Ka pipe ipin Aisaya 65

Wo Aisaya 65:12 ni o tọ