Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 63:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwọ ni baba wa.Bí Abrahamu kò tilẹ̀ mọ̀ wá,tí Israẹli kò sì dá wa mọ̀.Ìwọ OLUWA ni baba wa,Olùràpadà wa láti ìgbà àtijọ́, ni orúkọ rẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 63

Wo Aisaya 63:16 ni o tọ