Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 57:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí o bá kígbe,kí àwọn ère tí o kó jọ gbà ọ́.Atẹ́gùn lásán ni yóo gbé gbogbo wọn lọAfẹ́fẹ́ ni yóo fẹ́ wọn lọ.Ṣugbọn ẹni tí ó bá sá di mí,ni yóo ni ilẹ̀ náà,òun ni yóo sì jogún òkè mímọ́ mi.

Ka pipe ipin Aisaya 57

Wo Aisaya 57:13 ni o tọ