Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 55:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Kí eniyan burúkú fi ọ̀nà ibi rẹ̀ sílẹ̀,kí alaiṣododo kọ èrò burúkú rẹ̀ sílẹ̀,kí ó yipada sí OLUWA,kí OLUWA lè ṣàánú rẹ̀.Kí ó yipada sọ́dọ̀ Ọlọrun wa,nítorí Ọlọrun yóo dáríjì í lọpọlọpọ.

Ka pipe ipin Aisaya 55

Wo Aisaya 55:7 ni o tọ