Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 55:1 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní,“Gbogbo ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ,ẹ máa bọ̀ níbi tí omi wà;bí ẹ kò tilẹ̀ lówó lọ́wọ́,ẹ wá ra oúnjẹ kí ẹ sì jẹ.Ẹ wá ra ọtí waini láì mú owó lọ́wọ́,kí ẹ sì ra omi wàrà, tí ẹnikẹ́ni kò díyelé.

Ka pipe ipin Aisaya 55

Wo Aisaya 55:1 ni o tọ