Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 5:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ni inú ṣe bí OLUWA sí àwọn eniyan rẹ̀,ó sì na ọwọ́ rẹ̀, ó sì pa wọ́n,àwọn òkè sì mì tìtì.Òkú wọn dàbí pàǹtí láàrin ìgboro,sibẹsibẹ inú OLUWA kò rọ̀,bẹ́ẹ̀ ni kò sì dá ọwọ́ ìjà dúró.

Ka pipe ipin Aisaya 5

Wo Aisaya 5:25 ni o tọ