Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 48:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo ti sọ fun yín láti ọjọ́ pípẹ́:kí wọn tó ṣẹlẹ̀, mo ti kéde wọn fun yín,kí ẹ má baà sọ pé, ‘oriṣa wa ni ó ṣe wọ́n,àwọn ère wa ni ó pàṣẹ pé kí wọn ṣẹlẹ̀.’

Ka pipe ipin Aisaya 48

Wo Aisaya 48:5 ni o tọ