Òùngbẹ kò gbẹ wọ́n,nígbà tí ó mú wọn la inú aṣálẹ̀ kọjá,ó tú omi jáde fún wọn láti inú àpáta,ó la àpáta, omi sì tú jáde.