Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 48:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ jáde kúrò ní Babiloni,ẹ sá kúrò ní Kalidea,ẹ sọ ọ́ pẹlu ayọ̀,ẹ kéde rẹ̀,ẹ máa ròyìn rẹ̀ lọ títí dè òpin ayé, pé“OLUWA ti ra Jakọbu iranṣẹ rẹ̀ pada.”

Ka pipe ipin Aisaya 48

Wo Aisaya 48:20 ni o tọ