Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 45:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ sọ̀rọ̀ jáde, kí ẹ sì ro ẹjọ́ tiyín,jẹ́ kí wọ́n jọ gbìmọ̀ pọ̀.Ta ló sọ èyí láti ìgbà laelae?Ta ló kéde rẹ̀ láti ìgbà àtijọ́?Ṣebí èmi OLUWA ni?Kò tún sí Ọlọrun mìíràn lẹ́yìn mi.Ọlọrun Olódodo ati Olùgbàlàkò tún sí ẹnìkan mọ́, àfi èmi.

Ka pipe ipin Aisaya 45

Wo Aisaya 45:21 ni o tọ