Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 45:20 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní:“Ẹ kó ara yín jọ kí ẹ wá,ẹ jọ súnmọ́ bí,gbogbo ẹ̀yin tí ẹ kù ninu àwọn orílẹ̀-èdè.Aláìlóye ni àwọn tí ń gbẹ́ ère igi lásán kiri,tí wọ́n sì ń gbadurasí oriṣa tí kò lè gbànìyàn là.

Ka pipe ipin Aisaya 45

Wo Aisaya 45:20 ni o tọ