Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 42:16 BIBELI MIMỌ (BM)

“N óo darí àwọn afọ́jú,n óo mú wọn gba ọ̀nà tí wọn kò mọ̀ rí,n óo tọ́ wọn sọ́nà,ní ọ̀nà tí wọn kò mọ̀ rí.N óo sọ òkùnkùn di ìmọ́lẹ̀ níwájú wọn,n óo sì sọ àwọn ibi tí ó rí pálapàla di títẹ́jú.N óo ṣe àwọn nǹkan,n kò sì ní kọ̀ wọ́n sílẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 42

Wo Aisaya 42:16 ni o tọ