N óo sọ àwọn òkè gíga ati àwọn kéékèèké di ilẹ̀,n óo mú kí gbogbo ewéko orí wọn gbẹ;n óo sọ àwọn odò di erékùṣù,n óo sì mú kí àwọn adágún omi gbẹ.