Àwọn tí OLUWA rà pada yóo pada,wọn óo wá sí Sioni pẹlu orin,ayọ̀ ayérayé yóo kún inú wọn.Wọn óo rí ayọ̀ ati ìdùnnú gbàìbànújẹ́ ati òṣé yóo sá kúrò níbẹ̀.