Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 34:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn mààlúù igbó yóo kú pẹlu wọn,bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn ẹgbọ̀rọ̀ mààlúù ati àwọn akọ mààlúù ńlá.Ilẹ̀ wọn yóo kún fún ẹ̀jẹ̀,ọ̀rá eniyan yóo sì mú kí ilẹ̀ wọn lẹ́tù lójú.

Ka pipe ipin Aisaya 34

Wo Aisaya 34:7 ni o tọ