Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 34:6 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní idà kan tí a tì bọ inú ẹ̀jẹ̀,a rì í sinu ọ̀rá,pẹlu ẹ̀jẹ̀ ọ̀dọ́ aguntan ati ti ewúrẹ́,ati ọ̀rá ara kíndìnrín àgbò.Nítorí pé OLUWA yóo rú ẹbọ ní Bosira,yóo sì pa ọpọlọpọ eniyan ní ilẹ̀ Edomu.

Ka pipe ipin Aisaya 34

Wo Aisaya 34:6 ni o tọ