Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 21:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ bu omi wá fún ẹni tí òùngbẹ ń gbẹ.Ẹ gbé oúnjẹ pàdé ẹni tí ń sá fógun, ẹ̀yin ará ilẹ̀ Tema.

Ka pipe ipin Aisaya 21

Wo Aisaya 21:14 ni o tọ