Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Àsọtẹ́lẹ̀ nípa aṣálẹ̀ etí òkun nìyí:àjálù kan ń já bọ̀ láti inú aṣálẹ̀,láti ilẹ̀ tí ó bani lẹ́rù,ó ń bọ̀ bí ìjì líle tí ń jà bọ̀ láti ìhà àríwá aṣálẹ̀.

Ka pipe ipin Aisaya 21

Wo Aisaya 21:1 ni o tọ