Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 17:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìró àwọn orílẹ̀-èdè dàbí ti omi òkun ńláṣugbọn OLUWA yóo bá wọn wí wọn óo sì sá lọ.Wọn óo dàbí ìràwé tí afẹ́fẹ́ ń gbé lọ lórí òkè,ati bí eruku tí ìjì líle ń fẹ́ kiri.

Ka pipe ipin Aisaya 17

Wo Aisaya 17:13 ni o tọ