Ẹ gbọ́ ariwo ọ̀pọ̀ eniyan,wọ́n ń hó bí ìgbì òkun.Ẹ gbọ́ ìró àwọn orílẹ̀-èdèwọ́n ń hó bíi ríru omi òkun ńlá.