Mààlúù ati ẹranko beari yóo jọ máa jẹun pọ̀,àwọn ọmọ wọn yóo jọ máa sùn pọ̀,kinniun yóo sì máa jẹ koríko bí akọ mààlúù.