Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 11:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìkookò yóo máa bá ọ̀dọ́ aguntan gbé,àmọ̀tẹ́kùn yóo sùn sílẹ̀ pẹlu ọmọ ewúrẹ́,ọmọ mààlúù, ati kinniun, ati ẹgbọ̀rọ̀ ẹran àbọ́pa yóo jọ máa gbé pọ̀,ọmọ kékeré yóo sì máa kó wọn jẹ.

Ka pipe ipin Aisaya 11

Wo Aisaya 11:6 ni o tọ