Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Aisaya 1:18 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA ní, “Ẹ wá ná, ẹ jẹ́ kí á jọ sọ àsọyé pọ̀.Bí ẹ̀ṣẹ̀ yín tilẹ̀ pọ́n bí iná,yóo di funfun bí ẹfun.Bí ó tilẹ̀ pupa bí aṣọ àlàárì,yóo di funfun bí irun ọmọ aguntan funfun.

Ka pipe ipin Aisaya 1

Wo Aisaya 1:18 ni o tọ