Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Títù 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

láti jẹ́ ẹni ìwọ̀ntúnwọ̀nsì àti ọlọ́kàn mímọ́, kí wọ́n máa ṣe ojúse wọn nínú ilé, wọ́n gbọdọ̀ jẹ́ onínú rere, kí wón sì máa tẹríba fún àwọn ọkọ wọ́n, kí ẹnikẹ́ni máa baà sọ̀rọ̀ òdì sí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Títù 2

Wo Títù 2:5 ni o tọ