Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 4:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti baba àwọn tí ìkọlà tí kì í ṣe pé a kàn kọlà fún ṣá, ṣùgbọ́n ti wọn ń tẹ̀lé àpẹẹrẹ ìgbàgbọ́ tí baba wa Ábúráhámù ní, kí a tó kọ ọ́ nílà.

Ka pipe ipin Róòmù 4

Wo Róòmù 4:12 ni o tọ