Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 4:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì gbé àmì ìkọlà, èdìdì òdodo ìgbàgbọ́ tí ó ní nígbà tí ó wà ní àìkọlà kí ó lè ṣe baba gbogbo àwọn tí ó gbàgbọ́, bí a kò tilẹ̀ kọ wọ́n ní ilà kí a lè ka òdodo sí wọn pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Róòmù 4

Wo Róòmù 4:11 ni o tọ