Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé nípa iṣẹ́ òfin, a kì yóò dá ẹnikẹ́ni láre níwájú rẹ̀: nítorí nípa òfin ni ìmọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ ti wá.

Ka pipe ipin Róòmù 3

Wo Róòmù 3:20 ni o tọ