Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Róòmù 2:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìkọlà ní èrè nítòótọ́, bí ìwọ bá pa òfin mọ́; ṣùgbọ́n bí ìwọ bá jẹ́ arúfin, ìkọlà rẹ di àìkọlà.

Ka pipe ipin Róòmù 2

Wo Róòmù 2:25 ni o tọ